Matthew 20:20

Ẹ̀bẹ̀ ìyá

20 a bNígbà náà ni ìyá àwọn ọmọ Sebede bá àwọn ọmọ rẹ̀ wá sọ́dọ̀ Jesu, ó wólẹ̀ lórí eékún rẹ̀, o béèrè fún ojúrere rẹ̀.

Copyright information for YorBMYO